Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Robert Mugabe: Ọmọ Káfíńtà, olùkọ́ àti akọni òṣèlú níí ṣe
Published
Gẹ́gẹ́ bí olóòtú ìjọba àkọ́kọ́, tó sì tún padà jẹ Ààrẹ lórílẹ́èdè Zimbabwe, Robert Mugabe pinnu áti ṣe ìjọba àwa arawa, tó fi mọ́ ìpẹ̀tùsááwọ̀ tó mú yányán.