Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Mò ń kí BBC Yorùbá kú ayẹyẹ ọdún méjí láti orílẹ̀èdè Brazil - Mike Ifabunmi
Published
Ka to wi ka to fọ ka to ṣẹju pẹrẹ, ọdun meji ti pe. Ọmọ kekere ana ti wa wa dagba.