Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Obinrin Akansẹ: Ẹsẹ kiku bi ojo kọ mi lati di alagbara
Published
Nigba ti Aya bẹrẹ, o fi da olukọni rẹ loju wipe oun yoo se daradara.
O ni bi obinrin ba se aseyọri, ọkunrin fẹ maa n fa wọn sẹyin.