Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Davido fi ọkọ̀ Porsche ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí fún Chioma Avril
Published
Davido fi da loju Chioma pe oun kò ni pẹ́ fe laipẹ léyin to kọ́ka fi àwo orin tuntun to pe ni assurance pọ́n Chioma lé pé òun fẹ́ràn rẹ̀ púpọ̀.