Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Funke Olakunrin Burial: Ọ̀gọ̀rọ̀ èèyàn péjú síbi ìṣẹ̀yẹ ìkẹyìn f'ẹ́ni re tó lọ
Published
Tonílé, tàlejò ló péjú pésẹ̀ síbi ìsìnkú arábìnrin Funke Olakunrin táwọn agbébọn ṣekúpa nígbà tó ń rìnrìn àjò.