Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Nollywood: Motilola Adekunle gbajugbaja òṣere tiata fi àyà gbàngbà rẹ̀ hàn lórí ètò "Ṣé o láyà"
Published
Gbajugbaja oṣere tiata Yoruba,Motilọla Adekunle tó wa sí orí ètò ṣé o láyà ló ti fihan gbangba pe ọmọ Yoruba atata ni oun.
Ori eto ṣe o laya ti BBC News Yoruba lo ti dahun awọ̀n ibeere to jẹ mọ̀ asa, iṣesi ati owe Yoruba.
Ẹ wo ẹ̀kunrẹ̀rẹ̀ fidio bi arabinrin Motilola ṣe fakọ̀ yọ̀: