Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
2023 Elections: Ṣíṣe àfiwé ìlànà àfojúsùn ẹgbẹ́ òṣèlú kọ̀ọ̀kan fétò ìdìbò
Published
Bi eto idibo 2023 se n sunmọle, BBC Yoruba se akojọpọ iroyin nipa àfiwé ìlànà àfojúsùn ẹgbẹ́ òṣèlú kọ̀ọ̀kan fétò ìdìbò 2023.
Ẹ wa wo awọn ilana ẹgbẹ oselu kọọkan, afojusun wọn ati ọpọ ileri ti wọn n se fun yin ti wọn ba de ipo.