Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Arap Moi: Ọdún mẹ́rìnlélógún ló fi darí Kenya, tó sì di apàṣẹ wàá
Published
Bi itan aye Daniel Arap Moi se lọ ree, ẹni to fi ọdun mẹrinlelogun tukọ orilẹede Kenya.