Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Báwo ni àgbà òṣèré, Joke Muyiwa ṣe l'áyà tó?
Báwo ni àgbà òṣèré, Joke Muyiwa ṣe l'áyà tó?
Published
Gbajumọ oṣere tiata, Joke Muyiwa, kopa lori eto 'Se o laya' ni BBC Yoruba.
O dahun awọn ibeere to jẹ mọ asa, iṣesi ati owe Yoruba.
Bawo ni Joke Muyiwa ṣe ṣe lori eto naa? Ẹ fun oju yin l'ounjẹ