Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Enioluwa Adeoluwa ṣí igbá 'Ṣé o láyà' wò, ẹ wo ohun tí ojú rẹ̀ rí
Enioluwa Adeoluwa ṣí igbá 'Ṣé o láyà' wò, ẹ wo ohun tí ojú rẹ̀ rí
Published
Gbajumọ ilu, Ọgbẹni Enioluwa Adeoluwa, ti ọpọ ololufẹ rẹ mọ si Eni, kopa lori eto 'Se o laya' ni BBC Yoruba.
Lori eto naa ni awọn gbajumọ ilu ti ma n dahun awọn ibeere lori itan, aṣa ati iṣe Yoruba.
Bawo ni Enioluwa ṣe ṣe lori eto naa? Ẹ fun oju yin l'ounjẹ