Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Ishaq Oloyede: Jamb ko ni fi esi idanwo silẹ lẹsẹkẹsẹ
Published
Adari ajọ Jamb, Ọjọgbọn Ishaq Oloyede sọ wipe esi idanwo ti ọdun yii ko nii jade ni kia kia bi ti ọdun to kọja.