Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Ẹgbẹ ọmọ Yorùbá kí Gomina Abiola Ajimobi kú oríire ọjọ́ ìbí
Published
Agbarijọpọ ẹgbẹ awọn ọmọ bibi ilẹ Ibadan, Central Council of Ibadan Indigenes (CCII) n ṣe akanṣe eto igbalejo fun ayẹyẹ ọjọ ibi ọdun mọkandinlaadọrin ti gomina ipinlẹ Ọyọ, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi.
Ile isẹ iroyin BBC lo ni awọn aworan yii.