Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Yoruba to ti fẹ Fulani l'ọkọ fun ọdun metala
Published
Ọmọbinrin kan ni ilu Isẹyin, ti o ti fẹ Fulani lọkọ fun ọdun mẹtala so iri rẹ. O sọ iyatọ to wa laarin Bororo ati Fulani.