Ìwọ ń wo ẹ̀dà ọ̀rọ̀-nìkan ti ìkànnì yìí tí ó máa ń lo dátà díẹ̀. Wo ẹ̀dà àkọ́kọ́ ti ìkànnì náà pẹ̀lú gbogbo àwòrán àti fídíò.
Ìjíròrò láàrin àwọn olùdíje ipò gómìnà Èkó
Àlàyé àti èrò nípa ìjíròrò láàrin àwọn tó ń du ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Eko láti ìpàdé ìtagbangba BBC Yoruba.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Abdulwasiu Hassan
Ẹ káàbọ̀ !
Ẹ kú àbọ̀ sí ojú òpó tí a ó ti máa fún yín ní ìròyìn bó ṣe ń lọ níbi ìpàdé ìtagbangba BBC News Yorùbá fún àwọn olùdíje gómìnà ìpínlẹ̀ Eko.