BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ere Bọọlu
Spain júwe ilé fún Germany, Portugal ko àgbákò lọ́wọ́ France
6 Agẹmo 2024
Mbappe gbá góòlù méjì sáwọn lẹ́yìn tó bẹ̀rẹ̀ sí ní wọ ìbòjú gbá bọ́ọ̀lù
23 Òkùdu 2024
Wo ìdí tí àwọn agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà àtàwọn orílẹ̀èdè tó bá kópa ní ìdíje Afcon lọ́dún 2025 kò fi ní ṣe kérésimesì àti ọdún tuntun pẹ̀lú ẹbí wọn
22 Òkùdu 2024
Ìlànà ìdíje Premier League fún sáà 2024/2025 jáde, wo bí ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ẹgbẹ́ agb.abọ́ọ̀lù Arsenal, manchester City, Man Utd, Chelsea yóò ṣe rí
18 Òkùdu 2024
Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú àwọn eré bọ́ọ̀lù tó ti wáyé sẹ́yìn láàrin Nàìjíríà àti Benin Republic
10 Òkùdu 2024
Kí ni àwọn ànfàní tí George yóò mú fún Nàìjíríà nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ìdíje àgbáyé?
4 Òkùdu 2024
Wo agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà méjì míì tó ti mi àwọn nínú eré bọ́ọ̀lù àṣekágbá Europa League yàtọ̀ sí Lookman
23 Èbibi 2024
Chelsea fọwọ́ òsì júwe ilé fún akọ́nimọ̀ọ́gbá Pochettino lẹ́yìn oṣù mẹ́wàá
21 Èbibi 2024
Orúkọ ń ro ni! Oríògbadé FC padà mófo, Man City já ife ẹ̀yẹ EPL gbà mọ́ wọn lọ́wọ́
19 Èbibi 2024
Ṣé lóòtọ́ọ́ ni ìjàmbá ọkọ̀ ṣẹlẹ̀ sí Tijani Babangida agbábọ́ọ̀lù Náíjíríà tẹ́lẹ̀ rí?
10 Èbibi 2024
Ẹ̀gbin pọ̀ nínú iṣẹ́ mi ṣùgbọ́n mo ní àmójúkúrò - Bashir Alabi
15 Ìgbé 2024
Àwọn nǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìlànà tuntun tí UEFA gbé jáde fún Champions League
5 Ẹrẹ̀nà 2024
Wo iye ìgbà tí Nàìjíríà dé àṣekágbá ìdíje Afcon, àmọ́ tó bọ́ mọ́ wọ́n lọ́wọ́
12 Èrèlè 2024
Afcon 2023: Balógun ikọ̀ Super Eagles Williams Troost Ekong fojú sun ife ẹ̀yẹ Adúláwọ̀
10 Èrèlè 2024
Èèkàn ẹgbẹ́ APC jáde láyé níbi tó ti ń wo ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ Nàìjíríà àti South Africa ní Afcon, Tinubu kẹ́dùn
8 Èrèlè 2024
Ààrẹ Tinubu gbóríyìn fún Super Eagles, Ó níẹ̀bùn wà nílẹ̀ fún wọn
8 Èrèlè 2024
Ọmọ ológo Stanley Nwabali: Wo ohun tó yẹ kóo mọ̀ nípa àpáta nlá aṣọ́lé Nàìjíríà tó fakọyọ
8 Èrèlè 2024
Nigeria vs South Africa: Ìjà àgbà méjì láàrín Super Eagles àti Bafana Bafana ní Afcon 2023
7 Èrèlè 2024
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ bí Afcon Round of 16 yóò ṣe lọ
25 Sẹ́rẹ́ 2024
Èsì ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ gbogbo níbi ìdíje AFCON pẹ̀lú bí ìpín kọ̀ọ̀kan ṣe dúró
14 Sẹ́rẹ́ 2024
AFCON 2023: Ivory Coast f’àgbà han Guinea-Bissau pẹ̀lú àmì ayò méjì s’ódo
14 Sẹ́rẹ́ 2024
Àwọn àwòrán tó jojú-ń-gbèsè láti ibi ayẹyẹ ìṣíde ìdíje AFCON tò bẹ̀rẹ̀ ní Côte d'Ivoire
14 Sẹ́rẹ́ 2024
Ṣé lóòtọ́ ni CAF tún ní pé kí Kanga wá sọ ìdí tí Ìyá rẹ̀ fi kú lọ́dun 1986, tí wọ́n sì bí i lọ́dun 1990?
11 Sẹ́rẹ́ 2024
Akọ́nimọ̀ọ́gbà tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà, Broderick-Imasuen jáde láyé
4 Sẹ́rẹ́ 2024
Ìṣájú
Page
6
nínú
19
1
2
3
4
5
6
7
8
9
19
Tókàn