BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ofin
Ooni gbé ìgbésẹ̀ ọ̀tun lórí ẹ̀sùn jìbìtì owó àti ti ìgbéyàwó tí wọ́n fi kàn-án
25 Agẹmo 2024
Baba Mohbad ṣe àyẹ̀wò tuntun fún òkú ọmọ rẹ̀ láti mọ irú ikú tó pa á
24 Agẹmo 2024
Ó lé ní aláwọ̀ dúdú 39 tí mo ti pa, fúnra mi ni mo sì ń sọ fún ọlọ́pàá pé mo ti pààyàn
22 Agẹmo 2024
Ọmọ Nàìjíríà tó lé ní àádọ́ta táwọn kan fi ṣòwò ẹrú lọ Ghana ti móríbọ́ wálé
22 Agẹmo 2024
Obìnrin tó ṣẹ̀wọ̀n ọdún 43 fún ẹ̀sùn ìpànìyàn tí kò mọ̀ nípa rẹ̀ gbòmìnira
21 Agẹmo 2024
Ooni sọ̀rọ̀ lórí ẹ̀sùn jìbìtì $180,000 t’óbìnrin kan fi kàn án, ó ní ó tún kọ̀ láti fẹ́ òun
18 Agẹmo 2024
Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa aṣojú-ṣòfin nílùú Abuja tó kú lẹ́ni ọdún 39
17 Agẹmo 2024
Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Kano tún gbé òfin tuntun kalẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ Emir, àwọn ohun tó wà nínú rẹ̀ nìyí
16 Agẹmo 2024
Kíni ojúṣe ìgbìmọ̀ tí Makinde yàn lórí àwọn ìjọba ìbílẹ̀ tílé ẹjọ́ 'sọ di òmìnira'?
16 Agẹmo 2024
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn afurasí ajínigbé tó pa bàbá ẹni ọdún 71 lẹ́yìn tí wọ́n gbowó ìtúsílẹ̀ tán l’Ógùn
14 Agẹmo 2024
Wo ìhà tí àwọn wòlíì kọ sí òfin tí ìjọba fi de ìpéjọpọ̀ tako àwọn ẹlẹ́mìí òkùnkùn àti àjẹ́
14 Agẹmo 2024
Wo àwọn Ìpínlẹ̀ ní Nàìjíríà tó ṣeéṣe káwọn ìjọba ìbílẹ̀ wọn má rówó gbà bẹ̀rẹ̀ l'óṣù tó ń bọ̀ nítorí àìní alága
13 Agẹmo 2024
Ọba Olakuleyin gbọ̀pá àṣẹ gẹ́gẹ́ bí Olubadan Kẹtàlélógójì
12 Agẹmo 2024
Àpapọ̀ owó rìbá tí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba lórílẹ̀èdè Nàìjíríà gbà láàrín ọdún 2023 nìkan jẹ́ ₦721b
12 Agẹmo 2024
Nítorí ìdájọ mánigbàgé lórí òmìnira ìjọba ìbílẹ̀ yìí, àwọn èèyan wa yóò bẹ̀rẹ̀ síí fa àwọn adarí wọn lọ́rùn báyìí – Tinubu
12 Agẹmo 2024
Gbajúgbajà orí ayélujára Tiktok dèrò ẹ̀wọ̀n lóri pé ó sọ̀rọ̀ àbùkù sí ààrẹ
11 Agẹmo 2024
0:57
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 0,57
11 Agẹmo 2024
Lórí ìwọ́de Endsars, Ilé ẹjọ́ ECOWAS pàṣẹ fún ìjọba Naijiria láti san owó ìtanràn fún DJ Switch àtàwọn olùwọ́de méjì míràn
11 Agẹmo 2024
Èyí ni bí Canada ṣe di ibùba fún àwọn jàgùdà ajọ́kọ̀gbé lágbáyé
10 Agẹmo 2024
Àṣírí bí Emefiele ṣe fi òbítíbitì owó ránṣẹ́ láti CBN sí àpò àṣùwọ̀n ìyàwó rẹ̀ nílé-ẹjọ́
10 Agẹmo 2024
Ọwọ́ NDLEA tẹ Baálẹ̀ tó ń gbé igbó ní ìpínlẹ̀ Osun
7 Agẹmo 2024
Ẹ fura o! Ẹgbẹ́ òkùnkùn Aiye yóò ṣe ètò kan lónìí káàkiri Nàìjíríà tó lè m'éwu dání f'áráàlú - ilé-iṣẹ́ ọlọ́pàá
7 Agẹmo 2024
Ayàwòrán tó dáná sun fọ́to Ààrẹ gba ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n ọdún méji
6 Agẹmo 2024
Ọmọ ogun 25 gba ìdájọ́ ikú torí wọ́n jẹ́ ojo tó sá lójú ogun
5 Agẹmo 2024
Ìṣájú
Page
32
nínú
40
1
29
30
31
32
33
34
35
40
Tókàn