BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Egbẹ Oselu Onigbalẹ (APC)
Ohun tó ti yá kan kìí pẹ́ mọ́, fọ́ọ̀mù ìgbaniṣíṣẹ́ fún Àmọ̀tẹ́kùn dé!
7 Èrèlè 2020
Ẹ fi èmi àti àwọn alága káńṣù APC sílẹ̀, ká yanjú aáwọ̀ wa nítùbí-ǹnùbí - Makinde bẹ iléẹjọ́
6 Èrèlè 2020
Ṣíṣe iṣẹ́ ọlọ́pàá agbègbè láì gbowó, òfo ni - Onímọ̀ ètò ààbò
4 Èrèlè 2020
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ PDP tó sápamọ́ kọlù mí lásìkò tí mò ń lọ sí ibi iṣẹ́, ló fa rògbòdìyàn - Olamiju Akala
4 Èrèlè 2020
Jégéjégé la ó rún ọ̀kàdà àti kẹ̀kẹ́ Maruwa tí a bá mú l'Eko- Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
2 Èrèlè 2020
Owó ìjọba ìbílẹ̀ ló wọ àwọn alága káńṣù APC lójú l‘Ọyọ - Seyi Makinde
30 Sẹ́rẹ́ 2020
5:12
Fídíò,
Owó ìjọba ìbílẹ̀ làwọn alága káńṣù APC ranjú mọ́ l‘Ọyọ - Seyi Makinde
, Duration 5,12
30 Sẹ́rẹ́ 2020
Tìpá-tìkúúkùù, àwọn Alága Káńṣù l‘Ọyọ, tí Makinde fòfin dè yọjú síjọba ìbílẹ̀ wọn
28 Sẹ́rẹ́ 2020
Àgádágodo ní wọ́n fi ti ẹnú ọ̀nà káńṣù l‘Ọyọ, ọlọ́pàá gbàródan síbẹ̀
27 Sẹ́rẹ́ 2020
Ìjọba Ondo ṣetán láti san #30,000 gẹ́gẹ́ bí owó oṣù òṣìṣẹ́ tó kéré jùlọ
25 Sẹ́rẹ́ 2020
Fífẹ́ ju ìyàwó kan lọ ló mú ìṣẹ́ àti ìfàsẹ́yìn ba àpá àríwá Nàìjíríà- Lamido Sanusi
25 Sẹ́rẹ́ 2020
Mọ̀ síi nípa Bala Mohammed tílé ẹjọ́ pàṣẹ pé kó máa tukọ̀ ìpínlẹ̀ Bauchi lọ
21 Sẹ́rẹ́ 2020
Ẹ̀yin ẹ máà wò ó, ó ṣeéṣe kí APC túká lẹ́yìn ìṣèjọ́ba Buhari!
21 Sẹ́rẹ́ 2020
1:07
Fídíò,
Àwọn ọmọ ẹgbẹ́ PDP fẹ̀hónúhàn l'Abuja lórí ìdájọ́ ílé ẹjọ́ gíga jùlọ
, Duration 1,07
20 Sẹ́rẹ́ 2020
Àǹfààní wo ló wà nínú Brexit fún Nàìjíríà àtàwọn orílẹ́-èdè Afíríkà?
20 Sẹ́rẹ́ 2020
PDP yóò wọ́de nítorí ìdájọ́ ìdìbò gómìnà ìpínlẹ̀ Imo
19 Sẹ́rẹ́ 2020
Ẹgbẹ́ kan fún Tinubu ní wákàtí mẹ́rìnlélógún láti sọ èrò rẹ lórí Amọtẹkun
18 Sẹ́rẹ́ 2020
'Ẹ yé pè wá ní NEPA mọ́ tí ẹ bá fẹ́ ká fún yín ní iná, DisCos ni wá'
18 Sẹ́rẹ́ 2020
A ó sọ jálà bẹntiróò di N97 pẹ̀lúu lílo afẹ́fẹ́ gáàsì fún ọkọ̀ - Ìjọba
17 Sẹ́rẹ́ 2020
Ó pé ọdún mẹ́rìnlélàádọ̀ta tí Akintola kú, ìdí abájọ ìja rẹ̀ pẹ̀lú Awolowo rè é
15 Sẹ́rẹ́ 2020
Owó orí VAT di 7.5% láti 5% lẹ́yìn tí ààrẹ Buhari buwọ́lu àbá ètò ìnáwó
13 Sẹ́rẹ́ 2020
Ariwo kò jẹ́! A ti sún ìgbẹ́jọ́ Ganduje, Tambuwal àti Ihedioha sí ọ̀la
13 Sẹ́rẹ́ 2020
Amotekun dé! Ẹ̀yin ọmọ Yorùbá lókè òkun, ẹ má bẹ̀rù mọ́ láti wálé - Akeredolu
9 Sẹ́rẹ́ 2020
A móyè yìí jẹ... ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ fòǹtẹ̀ lú gómìnà mẹ́rin
8 Sẹ́rẹ́ 2020
Ìṣájú
Page
29
nínú
35
1
26
27
28
29
30
31
32
35
Tókàn