BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Aworan Fiimu
Ariwo ayọ̀ sọ nílé Remi Surutu, ọmọ rẹ̀ mú ọkọ wale
4 Ògún 2020
Aláàfin fẹ́ gba bàálù kékeré bíi owó orí mi, ọkọ mi ń gbọn kiri - Lizzy Anjorin
3 Ògún 2020
Àlàyé rèé lóríi àjọṣepọ̀ tó wà láàrin èmi àti MC Oluomo - Ronke Oshodi Oke
31 Agẹmo 2020
2:43
Fídíò,
Kò sí okùnrin tó fẹ́ gbé "Liability" sílé láyé òde òní- Ronke Ojo àti Toyin Lawani
, Duration 2,43
20 Òkùdu 2020
Dayo Amusa gbarata lórí bí agbófinró ṣe ń pa ọ̀dọ́ láì nídìí
29 Agẹmo 2020
Lizzy Anjọnrin fẹ̀si fáwọn agbọ́yì-sọ̀yí lórí ìgbéyàwó rẹ̀, Madam Sajẹ dasójú ilé iṣẹ́, àti àwọn ǹkan míràn tó ṣẹlẹ̀ lágbo tíátà lọ́sẹ̀ yìí
25 Agẹmo 2020
Funke Akindele fún mi lówó tí mo fi gba ilé, kò ra ilé fún mi o - Ajirebi
11 Agẹmo 2020
Erépá ní bàbá àti ìyá mi ṣe tí wọ́n fi bí mi, wọn kò fẹ́ra wọn- Funsho Adeolu
4 Agẹmo 2020
Baba Suwe bọ́ lọ́wọ́ àìsàn, ó bẹ̀rẹ̀ tíátà padà
1 Agẹmo 2020
Omijé bọ́ níbi ìsìnkú Ogun Majek
25 Òkùdu 2020
Bí àìsàn bàbà mi ṣe ń lọ, ló tún ń padà, kódà kò yé mi mọ- Ọmọ Bàbá Sùwé
17 Èbibi 2020
Ọ̀rọ̀ ìfẹ́ ti wọn fi ń lọ̀ mí lágbo àmúlùúdùn ni ìṣòro kan tí mo ní - Lizzy Jay ọmọ Ibadan
16 Èbibi 2020
O sàn ká wà láyé láì lówó lọ́wọ́ ju ká ya sinimá, ká kó Coronavirus lọ - Latin pariwo fáwọn òṣèré tíátà
15 Èbibi 2020
Èmi àti Sanyeri ti tọrọ oúnjẹ jẹ rí nílé oninawo torí ebi, ká tó di gbajumọ oṣere
7 Èbibi 2020
2:42
Fídíò,
Ìdí tí mo fi ṣe fíìmu àwòrán-dèèyàn 'Cartoon' nípa COVID-19-Niyi Akinmolayan
, Duration 2,42
5 Èbibi 2020
Duro Ladipọ, ìlúmọ̀ọ́ká òṣèré tíátà àti ọmọ àlúfà tí kò gbàgbé àṣà ìbílẹ̀
11 Ọ̀wàrà 2020
3:26
Fídíò,
Mo kan sara sawọn ayasọlo- Dayo Amusa
, Duration 3,26
30 Ìgbé 2020
Ẹ wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tíátà tó jogún eré ṣíṣe lọ́dọ̀ òbí wọn
29 Ìgbé 2020
Bukky Wright ṣ'ọjọ́ ìbí, Lizzy Anjorin f'orin bọnu, Femi Adebayo sọ ẹran àgbò rẹ̀ lórúkọ tuntun
5 Ìgbé 2020
Àwọn ojú oge Yollywood t'ọ́jà wọ́n ṣì ń tà wàràwàrà
2 Ìgbé 2020
5:22
Fídíò,
E yé ṣíra yín s'íhòhò nínú fíìmù, àṣà burúkú ni- Efusetan kìlọ̀ fáwọn òṣèré
, Duration 5,22
23 Ẹrẹ̀nà 2020
Òṣèré tíátà Yorùbá mẹ́ta gbàmì ẹ̀yẹ pé wọ́n pegedé
15 Ẹrẹ̀nà 2020
Eré apanilẹ́rìn ké kè ké lórí ayélujára ti ṣí ọ̀pọ̀ ìlẹ̀kùn fún mi - Mr Macaroni
14 Ẹrẹ̀nà 2020
Pa Kasumu tó ni ohùn ló lọ,ohùn tó fi sílẹ̀ kò ní parẹ́
2 Ẹrẹ̀nà 2020
Ìṣájú
Page
33
nínú
37
1
30
31
32
33
34
35
36
37
Tókàn