BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ere ori Itage
Mo gbìyànjú láti ṣẹ́yún àkọ́bí mi saájú ìgbeyàwó - Iyabo Ojo
10 Ìgbé 2022
Ìtara láti du ẹ̀mí mi gbópọn si torí ìfẹ́ tẹ fi hàn mí - Kemi Afolabi
10 Ìgbé 2022
Mo tọrọ àforíjì pé mo parọ́ ìgbéyàwó! Mi ò ṣe ìgbéyàwó kankan!
8 Ìgbé 2022
7:52
Fídíò,
ìdí tí mi ò lè fi àṣà Yorùbá àti ọ̀rọ̀ Ifá sílẹ̀ títí d'ọjọ́ alẹ́ rèé - Jimi solanke
, Duration 7,52
8 Ìgbé 2022
Wo ǹkan tí o kò mọ̀ nípa ESABOD tí òun àti Lizzy Anjorin jọ ń fi omi èpè wẹ ara wọn
7 Ìgbé 2022
Wo ohun tí Arike ṣe nínú ìjà yìí tí Màmá ESABOD ń wọ́ ọ nílẹ̀ tuurutu tèpètèpè?
6 Ìgbé 2022
7:46
Fídíò,
Olaiya Igwe ló wá ra epo nílé epo tí mo ti ń ṣiṣẹ́, mo bá bẹ́ mọ́ ọ, bí ayé mi ṣe yí padà di òṣèré fíìmù rèé
, Duration 7,46
6 Ìgbé 2022
"Mo sá fún oògùn owó, igbó mímu, mo tún ní sùúrù fún ọdún 15 kí n tó di olókìkí"
4 Ìgbé 2022
A máa ń lọ yọjú wo Yinka Quadri tó bá ń ṣe fíìmù ládùúgbò wa - Ẹ wo bí Dejo Tunfulu ṣe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Tíátà
4 Ìgbé 2022
Ó bọ́ mọ́ Wizkid, Femi Kuti, Burna Boy lọ́wọ́ ní Grammy Awards, wo àwọn tí wọ́n jọ figagbága
4 Ìgbé 2022
Wèrè ọlọ́mọ ní Dejo Tunfulu, ọmọ mẹ́rin ní ìyá wa dà sílẹ̀ fún, tó sì bá ọkọ míì lọ - Ọmọ olóògbé
2 Ìgbé 2022
Lukuluku Bantashi, ọdún 27 lẹ́yìn ikú gbajúmọ̀ aláwàdà
2 Ìgbé 2022
Baba Ijesha ń fẹ́ Princess, ìyá Princess gan sọ lójú mi pé kó tọ́jú ọmọ òun dáadáa - Ẹlẹ́rìí Kẹrin
2 Ìgbé 2022
Ikú Dejo Tunfulu ti kó ìrẹ̀wẹ̀sí ọkàn bá mi, ń kò le kópa nínú eré tà ń yà mọ́ - Ọ̀gá Bello
1 Ìgbé 2022
Kemi Afolabi ti nílò ìtọ́jú pàjáwìrì, a ń gbe lọ sókè òkun - Yomi Fabiyi bú sẹ́kún
29 Ẹrẹ̀nà 2022
Agbẹjọ́rò mi yóò tẹsẹ̀ òfin bọ ìṣẹ̀lẹ̀ Shoprite àmọ́ àwọn aláṣẹ ibùdó ìtajà náà sì ń bẹ̀ mí lọ́wọ́ - Toyin Asewo to re Mecca
28 Ẹrẹ̀nà 2022
Toyin Asewo to re Mecca fa wàhálà nílé ìtajà ShopRite n‘Ibadan lórí ẹ̀sùn ìbanilórúkọ jẹ́
27 Ẹrẹ̀nà 2022
5:48
Fídíò,
Wọ́n fi májèlé sínú gbogbo òúnjẹ́ ti mo rà sílé, ohun tí mo sọ fún ẹni náà rèé - Paramount Komedy
, Duration 5,48
26 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọ̀rọ̀ tí Kemi Afolabi sọ síta lẹ́yìn táwọn kan ráńṣẹ́ síi torí ìtọ́jú àìsàn Lupus tó ní
25 Ẹrẹ̀nà 2022
6:18
Fídíò,
Samuel Ajirebi ọmọ ọdún mẹ́rin àtijọ́ rèé, ó bojú wo fíìmù rẹ̀ ní kékére, máàkì tó fún ara rẹ̀ rèé
, Duration 6,18
23 Ẹrẹ̀nà 2022
Báwo ní àláfíà ara Iyabo Oko, ipò wo ní ìlera rẹ̀ wà?
18 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ gbà mi o, àwọn oníjìbìtì ayélujára ti ń bèèrè ìrànwọ́ lórúkọ́ mi - Kemi Afolabi lọgun
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹsẹ̀ mi yẹ̀ gẹ̀rẹ̀, mo la orí mọ́ táísì, mo sì fẹ́ ẹ̀ pàdánù ọpọlọ nígbà tà ń ya fíìmù - Mide Martins
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Wo àwọn òṣèré tíátà tó ti fún Kemi Afolabi lẹ́bùn àtàwọn tó ń kíi lẹ́yìn tó kéde àìsàn rẹ̀
14 Ẹrẹ̀nà 2022
Ìṣájú
Page
16
nínú
33
1
13
14
15
16
17
18
19
33
Tókàn