BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ifi ẹhonu han
Sri Lanka yan ààrẹ tuntun lẹ́yìn tí ààrẹ tẹ́lẹ̀ sálọ lásìkò ìwọ́de aráàlú
20 Agẹmo 2022
Àwọn àgbẹ̀ yarí fún ìjọba Ondo lórí bó ṣe ń ta ilẹ̀ oko wọn
18 Agẹmo 2022
Fídíò ṣàfihàn bí àwọn ọ̀dọ́ ṣe ń lùwẹ̀ẹ́ nílé Ààre lẹ́yìn tí wọ́n yabò ọ́, wo bí ààrẹ ṣe fẹ́ kọ̀wé fipò sílè torí èyí
10 Agẹmo 2022
Afurasí Fulani darandaran gún èèyàn kan pa l‘Eko torí pé ọkọ̀ pa màálù kan
28 Òkùdu 2022
Ẹ wo bí wọ́n ṣe bẹ́ orí ènìyàn nitori ó sọ ọ̀rọ̀ òdì sí Anabi Muhammed (SAW)
29 Òkùdu 2022
Ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ ajìjàgbara ṣèwọ́de n'Ibadan torí ìkọlù agbébọn nílẹ̀ Yorùbá
15 Òkùdu 2022
A kò mọ ohunkóhun pé wọ́n mú afurasí lórí ìkọlù agbébọn ní Owo - ọlọ́pàá
10 Òkùdu 2022
Ọlọ́kadà pa ènìyàn kan l’Eko, àwọn ọ̀dọ́ jó ọ̀pọ̀ ọ̀kadà níná
9 Òkùdu 2022
Ológun ní kí aya mi bọ́ aṣọ kúrò lára, pa ọmọ mi mẹ́rin àtàwọn alátìlẹyìn mi - El Zakzaky
19 Ẹrẹ̀nà 2022
Ṣé lóòtọ́ọ́ ní àwọn awakọ̀ èrò fẹ́ ṣe ìwọ́de lónìí l‘Eko torí yíyọ MC Oluomo nípò?
16 Ẹrẹ̀nà 2022
Ìwà àtakò sí ìjọba ní bí ọlọ́pàá bá da iṣẹ́ sílẹ̀, kò tọ̀nà - Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
16 Ẹrẹ̀nà 2022
10:54
Fídíò,
Mo lo oṣù mẹ́ta ní àhámọ́ ológun àti DSS torí nọ́mbà Sunday Igboho tó wà lórí fóònù mi – Tula Oyo
, Duration 10,54
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Tẹ̀gbọ́n tàbúrò jí ọmọ ará àdúgbò gbé láti gbowó, àmọ́ wọn fún ní òògùn eku jẹ
13 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọjọ́ Ajé la bẹ̀rẹ̀ ìpè fún ìdásílẹ̀ Yoruba Nation padà - Akintoye
13 Ẹrẹ̀nà 2022
Kí ló wáyé níbi ìpàdé NANS àti ìjọba àpapọ̀? àlàyé rèé
1 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ̀yìn òfin tó fààyè gba lílo Hijab nílé ẹ̀kọ́ ní mo wà - Gomina Kwara
23 Èrèlè 2022
Aáwọ̀ APC fẹ́jú, igun kan ń gbé pósí kiri Eko lórúkọ Aregbesola
21 Èrèlè 2022
Àwọn alákatakíti ẹ̀sìn pa ọmọ-ogun Mali lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀ ti France kó ọmọogun rẹ̀ kúrò
20 Èrèlè 2022
Ìjọba Canada ṣetán láti gbẹ́sẹ̀ lé àkáùntì àwọn tó ń ṣẹ ìwọ́de táko abẹ́rẹ́ covid-19
16 Èrèlè 2022
6:20
Fídíò,
Krìsítẹ́nì àti Mùsùlùmí tako ara wọn lórí aáwọ̀ lílo Hijab tó wáyé ní Ijagbo
, Duration 6,20
9 Èrèlè 2022
Àwọn alákòsóo APC l‘Abuja ti gbàbọ̀dè, APC l‘Oyo sì le kùnà ìbò gómìnà - Adeseun
8 Èrèlè 2022
Ìdìbò láti yan olùdíje APC fún ipò gómìnà l'Ekiti ń parí lọ, àmọ́...
27 Sẹ́rẹ́ 2022
''A kò ní dẹ́kun ìfẹ̀hònúhàn àyàfi tí ìjọba àtàwọn aláṣẹ FUTA bá gbé ìgbésẹ̀ lórí ètò àbò àwa akẹ́kọ̀ọ́''
17 Sẹ́rẹ́ 2022
Òfo ni 'White Paper' Sanwo-Olu kò sí ǹkan tó n jẹ́ bẹ́ẹ̀ lábẹ́ òfin - Adegboruwa
3 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ìṣájú
Page
11
nínú
21
1
8
9
10
11
12
13
14
21
Tókàn