BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Kwara
Gómìnà àná Kwara, Abdulfatah Ahmed fojú ba ilé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ṣíṣe owó ìlú kúmọkùmọ
30 Ìgbé 2024
Ọ̀wọ́ngógó epo: Ìjọba Kwara bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti fi kélé òfin gbé àwọn alágbàtà tó n gbé epo pamọ́
30 Ìgbé 2024
Níbo lẹran màálú onímájèlé 50 kángun sí ní Ilorin lẹ́yìn tí ìjọba gbé ọjà ẹran Mandate tìpa?
21 Ìgbé 2024
Ọwọ́ tẹ ọmọ ọdún mẹrìnlélógún tó jí ara rẹ̀ gbé ní Kwara
20 Ìgbé 2024
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn 46 tó ń da omi àlááfíà Ilorin rú
19 Ìgbé 2024
Sẹnetọ Rafiu Adebayọ jáde láyé lẹ́ni ọdún 57
17 Ìgbé 2024
Ìjì ńlá sọ ọ̀pọ̀ èèyàn di aláìnílélórí ní Kwara
13 Ìgbé 2024
Dúkìá tó lé ní ₦360m ṣòfò bí ọjà Owódé ní ìlú Offa ṣe jóná
3 Ìgbé 2024
6:54
Fídíò,
'Mo di akọ̀wé àgbà lẹ́nu iṣẹ́ nítorí àwọn òbí kò fi mí sílẹ̀ pẹ̀lú ìpèníjà ara tí mo ní'
, Duration 6,54
30 Ẹrẹ̀nà 2024
Wo ohun tó mú ayẹyẹ ‘Palm Sunday’ ní Ilorin yàtọ̀ sí ti àgbàyé yòókù
24 Ẹrẹ̀nà 2024
Gómìnà Abdulrasaq, Emir Ilorin kẹ́dùn ìpapòdà Oloro ìlú Oro, Ọba Oyelaran tó wàjà
23 Ẹrẹ̀nà 2024
Èèmọ̀ wọ̀lú, afurasí sọ́jà kan gún DPO ọlọ́pàá lọ́bẹ ní Kwara
22 Ẹrẹ̀nà 2024
'Ilé olórogún kìí rọrùn, kódà kí ọwọ́ ìwọ ìyálé mọ́'
21 Ẹrẹ̀nà 2024
Ọ̀pọ̀ dúkìá ṣòfò níbi ìjàmbá iná tó ṣẹlẹ̀ nílùú Ilorin
21 Ẹrẹ̀nà 2024
Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́sàn-án lákàtà àwọn ajínigbé, òyìnbó China gbòmìnira ní Kwara
20 Ẹrẹ̀nà 2024
Wo ilé ẹ̀kọ́ tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ti ń jòkó kàwé lábẹ́ igi ní Kwara
20 Ẹrẹ̀nà 2024
Àwọn òntàjà ẹ̀yà Igbo fárígá nílùú Ilorin, wọ́n láwọn ò ní tajà f'ẹ́nikẹ́ni, àyàfi...
19 Ẹrẹ̀nà 2024
Oṣù mẹ́fà nínú ọdún ni mo fi ń ṣiṣẹ́ l’Amẹrika, owó rẹ̀ ni mo fi ń tún ìlú ṣe - Onidera
18 Ẹrẹ̀nà 2024
Ìbẹ̀rùbojo gbalẹ̀ lẹ́yìn tí táńkà tó gbé epo 50,000 lítà gbókìtì ní Ilorin
17 Ẹrẹ̀nà 2024
Bí ẹ kò bá san Bílíọ́nù kan Náírà, March 26 ni á pa akẹ́kọ̀ọ́ 287 tí a gbé pamọ́ - Ajínigbé
14 Ẹrẹ̀nà 2024
Ọlọ́pàá rí òkú ọ̀gá ẹgbẹ́ onímárúwá nílé àkọ́kù, wọ́n gé orí, ìdí àti ọrùn ọwọ́ rẹ̀ lọ
13 Ẹrẹ̀nà 2024
5:47
Fídíò,
"Àwọn ọmọ mi mẹ́tẹ̀ẹ̀ta kò kú ikú Ọlọ́run, ooru mọ́tò kọ́ ló pa wọn, ogun ilé olórogún ni"
, Duration 5,47
11 Ẹrẹ̀nà 2024
Akẹ́kọ̀ọ́ fásitì Kwasu mẹ́rin bínú lu akẹẹgbẹ́ wọn pa nítorí pé o ya àwòrán wọn
9 Ẹrẹ̀nà 2024
Ọkunrin kan gún olùṣọ́ ọgbà ẹ̀wọ̀n lọ́bẹ ní Kwara, ó tún yìnbọn mọ́ aráàlú kan
9 Ẹrẹ̀nà 2024
Ìṣájú
Page
10
nínú
21
1
7
8
9
10
11
12
13
21
Tókàn