BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Orilẹede Naijiria
Wo awakọ̀ tó yá ₦3.5m ní báǹkì láti fi polongo sáà kejì fún Tinubu, olóṣèlú méjì míràn l'Ekiti
10 Ọ̀wàrà 2026
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa àdínkù owó epo bẹntiróòlù tí ìjọba Nàìjíríà kéde
9 Ọ̀wàrà 2026
"Ẹ má ṣe rò pé nǹkan kan ló wà nídìí bààlúù tó já l'Ondo, èmi àtàwọn ẹbí mi ti wọ ọkọ̀ náà rí-Olórí ogun òfurufú
9 Ọ̀wàrà 2026
Ṣé lóòótọ́ ni pé ìjọba àpapọ̀ fẹ́ẹ́ dá 'sọbsidi' padà ló ṣe mú ẹ̀dínwó bá owó epo bẹntiróòlù NNPCL fún oṣù kan? Àlàyé rèé
9 Ọ̀wàrà 2026
Wo àwọn olóṣèlú tí wọ́n ṣèlérí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù ìbò fún Tinubu lọ́dún 2027
9 Ọ̀wàrà 2026
Èèmọ̀! Ọmọ wòlíì f'orúkọ wòlíì míràn lu jìbìtì, gba ₦18m lọ́wọ́ àwọn tó ń wá ojútùú sí ìṣòro ayè wọn lórí ayélujára
9 Ọ̀wàrà 2026
Èmi ò mọ̀ bóyá wọ́n sanwó ìtúsílẹ̀ kankan lórí àwọn àgùnbánirọ̀ tí wọ́n jí gbé n'Imo- Kọmíṣánnà ọlọ́pàá Imo
8 Ọ̀wàrà 2026
Mọ̀ nípa òfin ìṣàkóso gáréèjì ọkọ̀ èrò tí Adeleke buwọ́lù l'Osun lẹ́yìn rògbòdìyàn ẹgbẹ́ awakọ̀ èrò
8 Ọ̀wàrà 2026
2:42
Fídíò,
'A kò tíì ri ara bàlúù náà gan, awakọ̀ bàlúú yìí ni ì bá lè sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ ní pàtó - Gómìnà Lucky Aiyedatiwa
, Duration 2,42
8 Ọ̀wàrà 2026
Ohun tí a mọ̀ rèé nípa ọkunrin tó kú sínú bààlúú tó ń bọ̀ sí ìlú Eko láti Kenya
7 Ọ̀wàrà 2026
Àlàyé lórí ìgbà mẹ́wàá tí bààlúù ológun tí já láàárín ọdún márùn-ún ní Naijiria
7 Ọ̀wàrà 2026
3:41
Fídíò,
"Èéfín ti gba gbogbo ara bàlúù náà lófurufú, tí kìí bá ṣe pé awakọ̀ bàlúù náà dùú dáadáa ni, aráàlú gan ìbá kú nínú ìjàmbá náà"
, Duration 3,41
7 Ọ̀wàrà 2026
Èèyàn mílíọ́nù 103 ti forúkọ sílẹ̀ fún ìdìbò 2027, Eko, Kano, Kaduna ló pọ̀jù-INEC
6 Ọ̀wàrà 2026
Wo orúkọ àwọn èèyàn tó pàdánù ẹ̀mí wọn nínú ọkọ̀ òfurufú ọmogun Naijiria NAF 931 tó já ní Igbokoda l'Ondo
6 Ọ̀wàrà 2026
2:58
Fídíò,
Mi ò ní ẹ̀rí pé èmi ni mo bori ìbò ààrẹ lọ́dún 2023, ṣùgbọ́n mo mọ̀ pé èmi ni mo borí - Peter Obi
, Duration 2,58
6 Ọ̀wàrà 2026
Àjèjì kọ́ ló l'Eko, ẹni bá ń sọ pé Eko ò lólúwà fẹ́ fi ìwọ̀sí lọ̀ wá ni – Gbade Rhodes- Vivour
5 Ọ̀wàrà 2026
Ìjọba Tinubu yíì kì í bá ẹgbẹ òṣìṣẹ́ sọ àsọyépọ̀- Joe Ajaero, Ààrẹ NLC
4 Ọ̀wàrà 2026
2:11
Fídíò,
Ẹ wo bí àwọn Òyìnbó ṣe ń gbé àṣà àti ìṣe Yorùbá lárugẹ ní orílẹ̀-èdè Brazil
, Duration 2,11
4 Ọ̀wàrà 2026
Ohun tí ìṣèjọba Tinubu ní í ṣe pẹ̀lú ikú ìyá mi - Amaechi
4 Ọ̀wàrà 2026
Agbésùnmọ̀mì tún pa àgbẹ̀ 15 sínú oko, mẹ́ta di àwátì
3 Ọ̀wàrà 2026
Igbákejì ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá Naijiria ṣáájú àwọn agbófinró ní Imo láti wá àgùnbánirọ̀ 20 àtàwọn èrò mí-ìn tí ajínigbé gbé lọ
3 Ọ̀wàrà 2026
Àwọn ọmọ Nàìjíríà 105 mí-ìn tún dé láti South Africa, wọ́n ní ọ̀pọ̀ ló ti kú s'ájò
3 Ọ̀wàrà 2026
2:21
Fídíò,
Ìjìyà tó wà lábẹ́ òfin rèé fún ẹnikẹ́ni tó lọ́wọ́ sí 'dìbò kó o sebẹ̀'
, Duration 2,21
3 Ọ̀wàrà 2026
Igun ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ wo ló bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì oníkìlọ̀ ọlọ́jọ́ mẹ́ta? Àlàyé rèé
3 Ọ̀wàrà 2026
Ìṣájú
Page
3
nínú
40
1
2
3
4
5
6
7
8
40
Tókàn