Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo

Àkọlé fídíò, Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo
Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo
Published

Lara awọn oludije fun ipo aṣojuṣofin ni ile aṣojuṣofin ni Temilolu Nurudeen Ashamu jẹ. o ba BBC News Yoruba sọrọ lori awọn ohun to sun un de didu ipo yii ati awọn ipinnu rẹ fawọn eeyan ẹkun idibo ilu Ọyọ to fẹ ṣoju fun.