Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo
Awọn ọ̀dọ́ ní iṣẹ́ láti ṣe lórí ọ̀rọ̀ ìṣèjọba àti ìdàgbàsókè - Ashamu, olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo
Published
BBC News Yoruba ba Temilolu Nurudeen Ashamu, tii se olùdíje ilé aṣojúṣòfin nípínlẹ̀ Oyo labẹ ẹgbẹ oselu APM sọrọ lati mọ awọn afojusun rẹ.



