Wo bí o ṣe lè mọ̀ bóyá o wà lára àwọn tí yóò jẹ ànfààní ₦50,000 tí ìjọba ń pín fún mẹ̀kúnnù

Àkọlé fídíò, Wo bí o ṣe lè mọ̀ bóyá o wà lára àwọn tí yóò jẹ ànfààní ₦50,000 tí ìjọba ń pín fún mẹ̀kúnnù
Wo bí o ṣe lè mọ̀ bóyá o wà lára àwọn tí yóò jẹ ànfààní ₦50,000 tí ìjọba ń pín fún mẹ̀kúnnù
Published

Laipẹ yii ni ijọba apapọ kede lati maa fun awọn mẹkunnu ni ẹgbẹrun lọna aadọta Naira lati se iranwọ fun isẹ ati osi to n bawọn ọmọ ilẹ yii finra.

Amọ ọpọ araalu ni ko mọ ọna ti wọn le gba jẹ anfaani owo iranwọ naa.

BBC News Yoruba, ninu fidio yii, se alaye bi ẹni kọọkan se le jẹ anfaani owoya naa.